[Lyrics] Brymo - Adedotun
Posted by badgeemmybxt

(Verse 1)

Awon adan fo loke, won fanka s’oju orun, won ma mobi won lo, Eledua lon s’ke wonKo keyin sile ore oh, oun o’n wa o wa ni iwaju re(Chorus)Adedotun oun dawon la mi, ero gbogbo e bami gberin, Adedotun oh(Verse 2)Awon Adan fo loke, nigba igba won kun oju orun, won ma mo oun wonje, Eledua lo n so won lo n bo wonKo pawon sile ore oh, oun wa lo sokoto, o wa la po sokoto(Chorus)Adedotun oun dawon la mi, ero gbogbo e bami gberin, Adedotun oh(Outro)Ko pawon sile ore oh, oun o’n wa o wa ni iwaju re oh
‹‹ 1 Last
(Pages: 1 )